Ada Ameh
Ada Ameh jẹ́ òṣèré ará ìlú Nàìjíríà kan tí ó ti lò ju ọdún ogún lọ ní ilé-iṣẹ fíìmù ti Nàìjíríà àti pé ó ṣe àkíyèsí jùlọ fún ipa rẹ̀ bi Anita ni fiimu 1996 tí àkọlé rẹ̀jẹ́ “ Domitilla” àti bi Emu Johnson nínú eré aláàmì-ẹ̀ye ti àkọlé rẹ jẹ́ Johnsons . Ameh nínu The Johnsons ṣe ìfihàn lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn òṣèré Nollywood mìíràn bii Charles Inojie, Chinedu Ikedieze & Olumide Oworu .[2][3][4] Ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ àti ẹ̀kọ́Ameh, bótilẹ̀jépé o jẹ́ abínibí ti Idoma ni Ipinle Benue, a bí tí o si dàgbà nìi Ajegunle ni Ipinle Eko, apá ìhà ìwọ-oòrùn gúúsù ìwọ-oòrùn ti Nàìjíríà tí ó borí púpọ̀ nípasẹ̀ àwọn ènìyàn tí n sọ èdè Yorùbá ti Nigeria . Ameh gba ẹ̀kọ́ ilé-ìwé alàkọ̀bẹ̀rẹ̀ àti ilé-ìwé giga ni ipinlẹ Eko ṣùgbọ́n óó parí ilé-ìwé ọjọ́-orí 14.[5] Iṣẹ́Ameh Ní ọdún 1995 ní ìfọwọ́sí apákan ti ilé-iṣẹ́ fíìmù ti Nollywood àti gba ipò fíìmù àkọ́kọ́ rẹ ní ọdún 1996 níbití ó ti kópa bí Anita ní fiimu “Domitila” Fíìmù kan tí ó di iṣẹ́ àṣeyọrí . Fíìmù náà ṣe àgbékalè àti ṣe ìtọ́sọ́nà nípasẹ̀ Zeb Ejiro . Ameh tún ṣe ìfihàn nínu jara TV ti Nàìjíríà tí àkọ́lé rè jẹ́ the Johnsons èyítí o tun di iṣẹ́ àṣeyọrí tí ó gba àwọn àmì-ẹri .[6][7] Igbésí ayé ara ẹniAmeh Ní ọmọ obìnrin kan tí ó bí ní gbà tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìnlá. Ameh jẹ ẹniti ó ń sọ èdè míràn ati èdè abinibi agbègbè rẹ̀ ní èdè Idoma, Gẹẹsi, Yoruba ńsọ ọ́pọ́ èdè àtioèdèNí ọdún 2017 wón gbé àkọle olórí fún Ameh ni Ipinle Benue[8][9] Filmography tí ayàn
Eré Tẹlifiṣọ̀nù
Àkópó Ìtọ́kasí
|
Portal di Ensiklopedia Dunia